Yorùbá Bibeli

Eks 6:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si gbà nyin ṣe enia fun ara mi, emi o si jẹ́ Ọlọrun fun nyin: ẹnyin o si mọ̀ pe emi li OLUWA Ọlọrun nyin, ti o mú nyin jade kuro labẹ ẹrù awọn ara Egipti.

Eks 6

Eks 6:1-12