Yorùbá Bibeli

Eks 6:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si bá Mose ati Aaroni sọ̀rọ, o si fi aṣẹ fun wọn si awọn ọmọ Israeli, ati si Farao, ọba Egipti, lati mú awọn ọmọ Israeli jade ni ilẹ Egipti.

Eks 6

Eks 6:6-15