Yorùbá Bibeli

Eks 40:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si mù oróro itasori nì, iwọ o si ta a sara agọ́ na, ati sara ohun gbogbo ti o wà ninu rẹ̀, iwọ o si yà a simimọ́, ati gbogbo ohun-èlo rẹ̀: yio si jẹ́ mimọ́.

Eks 40

Eks 40:6-16