Yorùbá Bibeli

Eks 40:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi pẹpẹ ẹbọsisun si ẹnu-ọ̀na ibugbé agọ́ ajọ, o si ru ẹbọ sisun, ati ẹbọ ohunjijẹ lori rẹ̀; bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose.

Eks 40

Eks 40:20-30