Yorùbá Bibeli

Eks 40:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ta oróro si wọn li ori, bi iwọ ti ta si baba wọn li ori, ki nwọn ko le ma ṣe iṣẹ alufa fun mi: nitoriti itasori wọn yio jẹ́ iṣẹ-alufa lailai nitõtọ, lati irandiran wọn.

Eks 40

Eks 40:13-16