Yorùbá Bibeli

Eks 4:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, bi nwọn kò ba gbà ọ gbọ́, ti nwọn kò si fetisi ohùn iṣẹ-àmi iṣaju, njẹ nwọn o gbà ohùn iṣẹ-àmi ikẹhin gbọ́.

Eks 4

Eks 4:6-17