Yorùbá Bibeli

Eks 38:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si fi idẹ ṣe agbada na, o si fi idẹ ṣe ẹsẹ̀ rẹ̀, ti awojiji ẹgbẹ awọn obinrin ti npejọ lati sìn li ẹnu-ọ̀na agọ́ ajọ.

Eks 38

Eks 38:1-12