Yorùbá Bibeli

Eks 38:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ihò-ìtẹbọ fun opó wọnni jẹ́ idẹ; kọkọrọ opó wọnni ati ọjá wọn jẹ́ fadakà; ati ibori ori wọn jẹ́ fadakà; ati gbogbo opó agbalá na li a fi fadakà gbà li ọjá.

Eks 38

Eks 38:11-23