Yorùbá Bibeli

Eks 34:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ajọ aiwukàra ni ki iwọ ki o ma pamọ́. Ijọ́ meje ni iwọ o jẹ àkara alaiwu, bi mo ti paṣẹ fun ọ, ni ìgba oṣù Abibu: nitoripe li oṣù Abibu ni iwọ jade kuro ni Egipti.

Eks 34

Eks 34:15-28