Yorùbá Bibeli

Eks 33:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Emi o ṣe ohun yi ti iwọ sọ pẹlu: nitoriti iwọ ri ore-ọfẹ li oju mi, emi si mọ̀ ọ li orukọ.

Eks 33

Eks 33:7-23