Yorùbá Bibeli

Eks 32:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si sọ fun Mose pe, Lọ, sọkalẹ lọ; nitoriti awọn enia rẹ, ti iwọ mú gòke lati ilẹ Egipti wá, nwọn ti ṣẹ̀.

Eks 32

Eks 32:1-15