Yorùbá Bibeli

Eks 32:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si gbà wọn li ọwọ́ wọn, o si fi ohun-ọnà fifin ṣe e, nigbati o si dà a li aworan ẹgbọrọmalu tán: nwọn si wipe, Israeli, wọnyi li oriṣa rẹ, ti o mú ọ gòke lati ilẹ Egipti wá.

Eks 32

Eks 32:1-12