Yorùbá Bibeli

Eks 32:30 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe ni ijọ́ keji, ni Mose wi fun awọn enia pe, Ẹnyin dá ẹ̀ṣẹ nla: njẹ nisisiyi, emi o gòke tọ̀ OLUWA, bọya emi o ṣètutu fun ẹ̀ṣẹ nyin.

Eks 32

Eks 32:25-35