Yorùbá Bibeli

Eks 32:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana ni Mose duro li ẹnubode ibudó, o si wipe, Ẹnikẹni ti o wà ni ìha ti OLUWA, ki o tọ̀ mi wá. Gbogbo awọn ọmọ Lefi si kó ara wọn jọ sọdọ rẹ̀.

Eks 32

Eks 32:25-28