Yorùbá Bibeli

Eks 32:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aaroni si wi fun wọn pe, Ẹ kán oruka wurà ti o wà li eti awọn aya nyin, ati ti awọn ọmọkunrin nyin, ati ti awọn ọmọbinrin nyin, ki ẹ si mú wọn tọ̀ mi wá.

Eks 32

Eks 32:1-10