Yorùbá Bibeli

Eks 30:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si wẹ̀ ọwọ́ wọn ati ẹsẹ̀ wọn, ki nwọn ki o má ba kú: yio si di ìlana fun wọn lailai, fun u ati fun irú-ọmọ rẹ̀ lati irandiran wọn.

Eks 30

Eks 30:13-31