Yorùbá Bibeli

Eks 30:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe agbada idẹ kan, ati ẹsẹ̀ rẹ̀ idẹ, fun wiwẹ̀: iwọ o si gbẹ́ e kà agbedemeji agọ́ ajọ, ati pẹpẹ nì, iwọ o si pọn omi sinu rẹ̀.

Eks 30

Eks 30:14-28