Yorùbá Bibeli

Eks 28:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati eti ẹ̀wọn meji ni ki iwọ ki o so mọ́ oju-ìde mejeji, ki o si fi si ejika ẹ̀wu-efodi na niwaju rẹ̀.

Eks 28

Eks 28:19-27