Yorùbá Bibeli

Eks 28:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Okuta wọnni yio si wà gẹgẹ bi orukọ awọn ọmọ Israeli mejila, gẹgẹ bi orukọ wọn; bi ifin edidi-àmi; olukuluku gẹgẹ bi orukọ rẹ̀ ni nwọn o wà fun ẹ̀ya Israeli mejejila.

Eks 28

Eks 28:15-22