Yorùbá Bibeli

Eks 28:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iṣẹ-ọnà afin-okuta, bi ifin èdidi-àmi, ni iwọ o fin okuta mejeji gẹgẹ bi orukọ awọn ọmọ Israeli: iwọ o si dè wọn si oju-ìde wurà.

Eks 28

Eks 28:7-20