Yorùbá Bibeli

Eks 27:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si paṣẹ fun awọn ọmọ Israeli, ki nwọn ki o mú oróro olifi daradara ti a gún fun ọ wá, fun imọlẹ, lati mu ki fitila ki o ma tàn nigbagbogbo.

Eks 27

Eks 27:18-21