Yorùbá Bibeli

Eks 26:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe ojóbo aṣọ-alaró si eti aṣọ-tita kan lati iṣẹti rẹ̀ wá ni ibi isolù, ati bẹ̃ gẹgẹ ni iwọ o ṣe li eti ikangun aṣọ-tita keji, ni ibi isolù keji.

Eks 26

Eks 26:1-11