Yorùbá Bibeli

Eks 26:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ta aṣọ-ikele na si abẹ ikọ́ wọnni, ki iwọ ki o le mú apoti ẹrí nì wá si inu aṣọ-ikele nì: aṣọ-ikele nì ni yio si pinya lãrin ibi mimọ́ ati ibi mimọ́ julọ fun nyin.

Eks 26

Eks 26:23-37