Yorùbá Bibeli

Eks 26:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si ṣe aṣọ-ikele alaró, ati elesè-àluko, ati ododó, ati ọ̀gbọ olokùn wiwẹ ti iṣẹ ọlọnà: ti on ti awọn kerubu nì ki a ṣe e:

Eks 26

Eks 26:30-35