Yorùbá Bibeli

Eks 25:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ o si fi kìki wurà bò o, ninu ati lode ni iwọ o fi bò o, iwọ o si ṣe igbáti wurà sori rẹ̀ yiká.

Eks 25

Eks 25:2-18