Yorùbá Bibeli

Eks 23:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu iwọ kò gbọdọ pọ́n alejò kan loju: ẹnyin sa ti mọ̀ inu alejò, nitoriti ẹnyin ti jẹ́ alejò ni ilẹ Egipti.

Eks 23

Eks 23:8-13