Yorùbá Bibeli

Eks 19:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si wi fun Mose pe, Sọkalẹ, kìlọ fun awọn enia, ki nwọn ki o má ba yà sọdọ OLUWA lati bẹ̀ ẹ wò, ki ọ̀pọ ki o má ba ṣegbe ninu wọn.

Eks 19

Eks 19:18-25