Yorùbá Bibeli

Eks 19:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oke Sinai si jẹ́ kìki ẽfi, nitoriti OLUWA sọkalẹ sori rẹ̀ ninu iná: ẽfi na si goke bi ẽfi ileru, gbogbo oke na si mì tìtì.

Eks 19

Eks 19:16-25