Yorùbá Bibeli

Eks 12:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti emi o là ilẹ Egipti já li oru na, emi o si kọlù gbogbo awọn akọ́bi ni ilẹ Egipti, ti enia ati ti ẹran; ati lara gbogbo oriṣa Egipti li emi o ṣe idajọ: emi li OLUWA.

Eks 12

Eks 12:5-21