Yorùbá Bibeli

Eks 11:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si fi ojurere fun awọn enia na li oju awọn ara Egipti. Pẹlupẹlu Mose ọkunrin nì o pọ̀ gidigidi ni ilẹ Egipti, li oju awọn iranṣẹ Farao, ati li oju awọn enia na.

Eks 11

Eks 11:1-5