Yorùbá Bibeli

Eks 10:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mose si wipe, Awa o lọ ati ewe ati àgba, ati awọn ọmọkunrin wa ati awọn ọmọbinrin wa, pẹlu awọn agbo, ati ọwọ́-ẹran wa li awa o lọ; nitori ajọ OLUWA ni fun wa:

Eks 10

Eks 10:8-10