Yorùbá Bibeli

Eks 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si bò oju ilẹ ti ẹnikan ki yio fi le ri ilẹ: nwọn o si jẹ ajẹkù eyiti o bọ́, ti o kù fun nyin lọwọ yinyin, yio si jẹ igi nyin gbogbo ti o nruwe ninu oko.

Eks 10

Eks 10:1-11