Yorùbá Bibeli

Eks 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn iyãgbà si wi fun Farao pe, nitoriti awọn obinrin Heberu kò ri bi awọn obinrin Egipti; nitoriti ara yá wọn, nwọn a si ti bí ki awọn iyãgbà to wọle tọ̀ wọn lọ.

Eks 1

Eks 1:12-22