Yorùbá Bibeli

Eks 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi ìsin lile, li erupẹ ati ni briki ṣiṣe, ati ni oniruru ìsin li oko mu aiye wọn korò: gbogbo ìsin wọn ti nwọn mu wọn sìn, asìnpa ni.

Eks 1

Eks 1:13-18