Ahọn ọmọ-ọmu lẹ̀ mọ oke ẹnu rẹ̀ nitori ongbẹ: awọn ọmọ kekere mbere onjẹ, ẹnikan kò si bu u fun wọn.