Yorùbá Bibeli

Ẹk. Jer 1:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

On sọkun gidigidi li oru, omije rẹ̀ si wà ni ẹ̀rẹkẹ rẹ̀: lãrin gbogbo awọn olufẹ rẹ̀, kò ni ẹnikẹni lati tù u ninu: gbogbo awọn ọrẹ rẹ̀ ti ba a lo ẹ̀tan, nwọn di ọta rẹ̀.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:1-12