Yorùbá Bibeli

Ẹk. Jer 1:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Okùn àjaga irekọja mi li a dimu li ọwọ rẹ̀; a so wọn pọ̀: nwọn yi ọrùn mi ka, nwọn tẹ agbara mi mọlẹ; Oluwa ti fi mi le ọwọ awọn ẹniti emi kò le dide si.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:8-20