Yorùbá Bibeli

Ẹk. Jer 1:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Aninilara ti nà ọwọ rẹ̀ jade sori gbogbo ohun daradara rẹ̀: nitori on ti ri pe awọn orilẹ-ède wọ ibi-mimọ́ rẹ̀, eyiti iwọ paṣẹ pe, nwọn kì o wọ inu ijọ tirẹ.

Ẹk. Jer 1

Ẹk. Jer 1:9-11