Yorùbá Bibeli

Amo 9:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kiyesi i, Oluwa Ọlọrun mbẹ lara ilẹ ọba ti o kún fun ẹ̀ṣẹ, emi o si pa a run kuro lori ilẹ; ṣugbọn emi kì yio pa ile Jakobu run tan patapata, li Oluwa wi.

Amo 9

Amo 9:4-12