Yorùbá Bibeli

Amo 3:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pe, li ọjọ ti emi o bẹ̀ irekọja Israeli wò lara rẹ̀, emi o bẹ̀ awọn pẹpẹ Beteli wò pẹlu: a o si ké iwo pẹpẹ kuro, nwọn o si wó lulẹ.

Amo 3

Amo 3:7-15