Yorùbá Bibeli

A. Oni 7:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia na si mu onjẹ ati ipè li ọwọ́ wọn: on si rán gbogbo Israeli lọ, olukuluku sinu agọ́ rẹ̀, o si da ọdunrun ọkunrin nì duro: ibudó Midiani si wà nisalẹ rẹ̀ li afonifoji.

A. Oni 7

A. Oni 7:1-11