Yorùbá Bibeli

A. Oni 7:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹgbẹ mẹtẹta na si fun ipè wọn, nwọn si fọ́ ìṣa wọn, nwọn si mú awọn òtufu li ọwọ́ òsi wọn, ati ipè li ọwọ́ ọtún lati fun: nwọn si kigbe li ohùn rara pe, Idà OLUWA, ati ti Gideoni.

A. Oni 7

A. Oni 7:10-25