Yorùbá Bibeli

A. Oni 7:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati mo ba fun ìpe, emi ati gbogbo awọn ti mbẹ lọdọ mi, nigbana ni ki ẹnyin pẹlu ki o fun ìpe yiká gbogbo ibudó na, ki ẹnyin ki o si wi pe, Fun OLUWA, ati fun Gideoni.

A. Oni 7

A. Oni 7:17-19