Yorùbá Bibeli

A. Oni 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn Midiani ati awọn Amaleki, ati gbogbo awọn ọmọ ìha ìla-õrùn tò lọ titi li afonifoji gẹgẹ bi eṣú li ọ̀pọlọpọ; ibakasiẹ wọn kò si ní iye, bi iyanrin ti mbẹ leti okun li ọ̀pọlọpọ.

A. Oni 7

A. Oni 7:3-16