Yorùbá Bibeli

A. Oni 7:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBANA ni Jerubbaali, ti iṣe Gideoni, ati gbogbo awọn enia ti o wà pẹlu rẹ̀, dide ni kùtukutu, nwọn si dó lẹba orisun Harodu: ibudó Midiani si wà ni ìha ariwa wọn, nibi òke More, li afonifoji.

A. Oni 7

A. Oni 7:1-11