Yorùbá Bibeli

A. Oni 6:35 Yorùbá Bibeli (YCE)

On si rán onṣẹ si gbogbo Manasse; awọn si kójọ sẹhin rẹ̀ pẹlu: o si rán onṣẹ si Aṣeri, ati si Sebuluni, ati si Naftali; nwọn si gòke wá lati pade wọn.

A. Oni 6

A. Oni 6:28-40