Yorùbá Bibeli

A. Oni 6:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọwọ́ Midiani si le si Israeli: ati nitori Midiani awọn ọmọ Israeli wà ihò wọnni fun ara wọn, ti o wà ninu òke, ati ninu ọgbun, ati ni ibi-agbara wọnni.

A. Oni 6

A. Oni 6:1-4