Yorùbá Bibeli

A. Oni 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Israeli si ṣe eyiti o buru li oju OLUWA, nwọn si gbàgbé OLUWA Ọlọrun wọn, nwọn si nsìn Baalimu ati Aṣerotu.

A. Oni 3

A. Oni 3:5-16