Yorùbá Bibeli

A. Oni 3:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nigbati awọn ọmọ Israeli kigbepè OLUWA, OLUWA si gbé olugbala kan dide fun wọn, Ehudu ọmọ Gera, ẹ̀ya Benjamini, ọlọwọ́-òsi: awọn ọmọ Israeli si fi ẹ̀bun rán a si Egloni ọba Moabu.

A. Oni 3

A. Oni 3:14-25