Yorùbá Bibeli

A. Oni 21:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li awọn ọmọ Israeli si lọ lati ibẹ̀, olukuluku enia si ẹ̀ya tirẹ̀, ati si idile tirẹ̀, nwọn si jade lati ibẹ̀ lọ olukuluku enia si ilẹ-iní tirẹ̀.

A. Oni 21

A. Oni 21:21-25